Prof. Ajibade
PROFESSOR OF YORUBA LITERATURE
PROFESSOR OLÚSOLÁ GEORGE AJÍBÁDÉ.
Ní ojó kejìdínlógbòn osù karùn-ún odún 2019 ni Òjògbón Olúsolá George Ajíbádé se ayeye tí àwon gèésì ñ pè ní "Inaugural Lecture" ní ogbà Yunifásitì ti Obáfémi Awólówò. Òjògbón Ajíbádé O.G jé òjògbón nínú lítírésò Yorùbá. Òkan lára olùkó ni wón jé ní èka-èkó ìmò èdá èdè àti èdè adúláwò(Department of linguistics and African languages).

Email: solajibade@yahoo.com or ajibadeb@oauife.edu.ng
Tel:+2348062109625

Comments
Post a Comment