OMOGE OLÓSÀN
OMOGE OLÓSÀN
Ló se é mu.
Kò sí osàn re tí n ò lè kówólé,
Osàn re wù mí,
Ó momú láyà mi
Jé kí n gbénu si
Kó se gòòrògò láyà.
Kò sí osàn re tí kò léwé.
Kò sí osàn re tí kò dùn.
Bí wón ti n pè ó lótùn-ún
Náà ni wón n pè ó lósì.
"Omoge olósàn, ìwo là n pè
Sé oò ní jépè wa ni?
Bó síbí, mo fé musàn"
Gbogbo Ohun mo rí ló pó
n,Ló se é mu.
Kò sí osàn re tí n ò lè kówólé,
Osàn re wù mí,
Ó momú láyà mi
Jé kí n gbénu si
Kó se gòòrògò láyà.
Kò sí osàn re tí kò léwé.
Kò sí osàn re tí kò dùn.
Bí wón ti n pè ó lótùn-ún
Náà ni wón n pè ó lósì.
"Omoge olósàn, ìwo là n pè
Sé oò ní jépè wa ni?
Bó síbí, mo fé musàn"



Comments
Post a Comment